Ekiti Election: Èyí ń rán wa létí pé iná èèsì kò gbọdọ̀ jó wa ní ẹ̀ẹ̀kejì

Published

Awọn aworan yii lo n sọ nipa awọn isẹlẹ̀ to waye lọdun 2014 lasiko eto idibo gomina ni ipinlẹ Ekiti.

Awọn ọlọkada to pọ gbe oludije kan sori ọkada
Àkọlé àwòrán, Ẹni to wa lẹgbẹ to n sejọba lọwọ ni 2014, lo jẹ oludije fun ẹgbẹ alatako bayii
Ọpọ ero ni agọ idibo
Àkọlé àwòrán, Gaga lara awọn eeyan ya lati dibo
Ọpọ ero n yin oludije kan lawo
Àkọlé àwòrán, Ẹni ti aye n fẹ, kii ni abuku kan lara
Ọpọ eeyan lẹyin oludije kan
Àkọlé àwòrán, Ẹni ti ko lee rin, ni ki wọn wọ oun lasiko ipolongo ibo
Agọ ibo kan to kun fawọn to fẹ dibo
Àkọlé àwòrán, Oju ri lọjọ ibo
Ẹbọ kan niwaju ile
Àkọlé àwòrán, Ẹbọ gbigbe kan ko gbẹyin lasiko ibo
Ayọdele Fayose n lu ilu
Àkọlé àwòrán, Oludije kan n lu ilu fawọn eeyan jo
Ọpọ eeyan to n dibo
Àkọlé àwòrán, Ọ́pọ eeyan wọ oorun sori lati dibo
Awọn osisẹ Inec
Àkọlé àwòrán, Awọn osisẹ ajọ eleto idbo sisẹ kara
Awọn osisẹ agbofinro loju popo.
Àkọlé àwòrán, Kii se igba akọkọ ree tawọn agbofinro yoo peju sibi eto idibo, o ti waye saaju
Awọn oludibo ni agọ idibo
Àkọlé àwòrán, Tarugbo-tomidan lo jade lati dibo
Araalu kan n gbe ami atilẹyin fun oludije kan
Àkọlé àwòrán, Oludije kan ami iifẹ ati atilẹyin lọ̀wọ ololufẹ rẹ kan
Oludije fẹgbẹ PDP wọ ayẹta
Àkọlé àwòrán, Bi awọn olodije gomina se wọ ayẹta ni 2014, naa lawọn oludije goomina ni 2018 tun n wọ ayẹta ni Elkiti
Awọn ero pe jọ sọdọ Oludije kan
Àkọlé àwòrán, Bi oludije kan se n gba oriyin, naa ni omiran n gba