World Cup 2018: Ahmed Musa di ààyò ní Naijiria

Published

Oniruuru aworan Ahmed Musa ni awọn ọmọ Naijiria ya si ara nkan ni orisirisi.

Amed Musa lara iwe ipolongo ibo
Àkọlé àwòrán, Bi eegun ẹni ba jo re, ori a maa ya atọkun rẹ. Awọn ọmọ Naijiria n pe Ahmed Musa ko wa jẹ aarẹ Naijiria
Ahmed Musa
Àkọlé àwòrán, Naijiria fun Musa ni tikẹẹti lati dije du ipo Aarẹ lọfẹ lori ayelujara
Ahmed Musa
Àkọlé àwòrán, Ahmed Musa di aayo agbabọọlu tawọn ọmọ Naijiria n wari fun
Apo irẹsi pẹlu aworan Amed Musa
Àkọlé àwòrán, Ahmed Musa lawọn ọmọ Nigeria ri bii Olugbala ni gbogbo ẹka
Apo irẹsi pẹlu aworan Ahmed Musa
Àkọlé àwòrán, Koda awọn ọmọ Naijiria tun wwe Lawani fun Ahmed Musa gẹg bii alasẹ wọn
Ọwọ ti faanu ge
Àkọlé àwòrán, Ọkunrin yii ni Ahmed Musa lo jẹ ki faanu ge oun lọwọ nigba to fo soke nitori ayo ti Musa gba wọle
Ọkunrin kan yọ ikun silẹ
Àkọlé àwòrán, Saaju idije Super Eagles pẹlu Iceland ni ọkan awọn ọmọ Naijiria ko ti balẹ, wọn n gbadura si Ọlọrun ko ko awọn yọ
Amed Musa lara iwe ipolongo ibo
Àkọlé àwòrán, Bi eegun ẹni ba jo re, ori a maa ya atọkun rẹ. Awọn ọmọ Naijiria n pe Ahmed Musa ko wa jẹ aarẹ Naijiria