Sotitobiire: Mo gbàgbọ́ pé kò sí ǹkan tí Olọ́run kò lè ṣe - Bisola aya Wolii Alfa Sotitobiire

Àkọlé fídíò, A kò tíì dẹ́kun àdúrà pé kí àṣírí àwọn tó jí ọmọ gbé tú - Bisola Alfa Sotitobire
Published

A kò tíì dẹ́kun àdúrà pé kí àṣírí àwọn tó jí ọmọ gbé tú - Bisola Alfa Sotitobire

Arabinrin Bisola Alfa, aya Wolii Sotitobiire sọrọ ọpẹ ninu gbogbo ohun to ṣẹlẹ si ọkọ rẹ.

Bisola ni adura pe ki aṣiri awọn oniṣẹ ibi to ji Kolawole Gold gbe tu sita ni ijọ oun ṣi n gba.

Sotitobiire
Àkọlé àwòrán, Sotitobiire

O dupẹ lọwọ awọn Wolii tooto ati ọmọ Naijiria nile ati loke okun to satileyin fun Woli Alfa Sotitobiire.

Sotitobiire
Àkọlé àwòrán, Sotitobiire

Bakan naa ni arabinrin Bisola fi imoore re han si awon ọmọ ijọ Sotitobiire naa.

Sotitobiire
Àkọlé àwòrán, Sotitobiire