Poverty: Lati ogoji ọdun ni iyàn ti wọn ko ri ri ti m ba wọn ja nilu yii

Àkọlé fídíò, 'Àfi bí mo bá sunkún mọ́ títọrọ̀ owó, tórí gbobo wa ni ìyà ń jẹ níbí'
Published

Akọroyin: Nibo lo ti r'owo ra awọn oogun yii?

Scholastica: Mo tọrọ owo ni.

Oogun itọ ṣuga

Akọroyin: Amọ o yẹ ki o lo oogun na pẹlu ounjẹ

Scholastica: ...

Ìyá yìí ní láti yàn nínú oògùn tàbí oúnjẹ bẹ́ẹ̀ sì ni ìtọ̀ ṣúgà ń bá a fínra!

Scholastica

Bo ba tilẹ wa jẹ pe itọ ṣuga ọhun nikan ni iṣoro rẹ, ko ba dara tori itọju yoo yọju ṣugbọn ọrọ ko ri bẹ ni ilu kan lorilẹede Zimbabwe.

Lati ogoji ọdun ni iru iyàn ti wọn ko ri ri ti m ba wọn ja nilu yii.

Zimbabwe

Ko sounjẹ, ko sowo, inu ireti kan naa ni gbogbo wọn wa nitori naa, ẹni to fẹ tọrọ owo naa ko yatọ si ẹni to fẹ tọrọ lọwọ rẹ̀.

Scholastica