Revolution Now: Àwọn èèyàn tó ń ṣèwọ́de ní ẹ̀rù kò bà àwọn, awọn ṣetan láti wà ní àtìmọ́lé

Àkọlé fídíò, RevolutionNow: Ẹ̀rù ò bàwá, a ṣetan láti wà ní àtì mọ́lé- olùfẹ̀hónúhàn
Published

Ọ̀pọ̀ àwọn alátilẹ̀yìn RevolutionNow ló ti fáríga o pé àwọn ti sẹ́tàn fun gbogbo ìgbẹ́sẹ̀ ti ààrẹ Muhammedu Buhari bá fẹ́ gbé.

Wọ́n fí ìdi èyí múlẹ̀ lásìkò tí wọ́n ń wáde lọ́jọ́ ajé pé kí Buhari ko gbogbo àwọn sẹ́wọ̀n, súgbọ̀n kíi ààrẹ mọ pé ẹ̀yin ìgbẹ́sẹ̀ náà kò ní fararọ.