AFCON2019: Idije òní á yàtọ̀ láàrin Super Eagles ati BafanaBafana
Published
A n gbe ife ẹyẹ AFCON bọ wa sile ni.
Lala maa lu ni alẹ oni nigba ti Bafana Bafana ẹgbẹ agbabọọlu South Africa maa gbena woju Super Eagles ti Naijiria.
Idije AFCON ti ilẹ Adulawọ ṣi n lọ lọwọ ni orilẹ-ede Egypt to n gbalejo ẹ.
Ọpọ ninu awọn ọmọ Naijiria gba pe ori Aare Buhari maa n gba ife ẹyẹ pe ati pé pẹlu adura, o maa ja si ọpẹ.
- Ìjọba ló ń ṣe kóríyá fún àlàfo ńlá láàrin ọlọ́rọ̀ àti mẹ̀kúnnù - Oxfam
- Dúkìá àti ọkọ̀ jóná, ọlọ́pàá mẹ́sàn-án fara gbọta lásìkò ìwọ́de Shiite
- Gba owó lọ́wọ́ àkẹ́kọ̀ọ́ ìjọba, ko rugi oyin - Seyi Makinde
- Iṣu ló wà nínú mọ́tò mi, kìí ṣe èèyàn ni mo sọ di iṣu - Afurasí Ajínigbé figbe ta
- Ẹ yé irọ́ pa, mí o fún Super Eagles ní ẹbùn owó kánkan -Sanwo Olu