COZA: Ọpọ èrò ló jáde ṣe lòdì sí ẹ̀sùn ìfipábánilòpọ̀ Fatoyinbo

Àkọlé fídíò, COZA: Ọpọ èrò ló jáde ṣe lòdì sí ẹ̀sùn ìfipábánilòpọ̀ Fatoyinbo
Published

Busola Dakolo ló jáde fẹ̀sùn kan Pasitọ Biodun Fatoyinbo pé o fipá bá òun lò pọ̀ ni èyí tó mú kí àwọn èèyàn jáde sọ̀rọ̀.

Iwọde ṣe lodi si ẹsun ifipabanilopọ yii waye ni ilu Abuja to jẹ olu ilu Naijiria ati Ikeja ni ipinlẹ Eko.

Opo ninu awọn to ṣe iwọde na ni awọn jade ki ọrọ ifipabanilopọ le di ohun igbagbe ni Naijiria ni.