Ògidì ọmọ Yorùbá gbọ́dọ̀ kọ́ ọmọ rẹ̀ ni àṣà àti ìṣe Yorùbá
Published
Kìí bàá tì ni ẹni tí wọ́n bà pè ni atamátàsé nílẹ̀ Oodua.
Àmì orí 'atamatase' ni re-re-mi-do-mi.
Èdè olóhùn ni èdè Yorùbá. Àmì ohùn ni a fi ń ṣe ìyàtọ̀ sí ọ̀rọ̀ Yorùbá.
Àwọn kan gbà pé agbábọ́ọ̀lù iwájú (striker) ni atamátàsé to máa ń gbà bọ̀ọ́lù sáwọ̀n.
Àwọn míràn gbà pé ọ̀rọ̀ àpèjúwe ni atamátàsé to fihàn pé ẹni náà kìí kùnà tàbí kìí ṣe àṣìṣe rárá nítorí pé o mọ nkan ṣe lọna to yẹ.
BBC Yorùbá jáde láti dán ìmọ̀ àwọn ènìyán wo lọmode, lagba lori fifi àmì sí ọ̀rọ̀ Yorùbá.
Ẹ̀kọ́ èdè ati àṣà Yoruba ṣe pataki fún àwọn ògidì ọmọ Yoruba pàápàá lásìkò ìsinmi ti wọn wa yìí.

Àwọn iròyin tì ẹ leè ní ìfẹ̀ síí:
- Kí lẹ ò mọ̀ nípa àwọn obinrin Yollywood yìí?
- Ọ̀pọ̀ èrò gbàgbọ́ pé òrìṣà ni àfín jẹ́ láwùjọ
- 'Dokita ilé ìwòsàn ló gba ẹsẹ̀ lọ́wọ́ mi'
- 'APC kò fẹ́ ire fún mi mọ́ nínú ìṣesí wọn'
- 'Ọṣinbajo jọmí lójú pẹ̀lú ìwà akin tó hù'
- Iyàwó dùn lọ́sìngín ni ọ̀rọ̀ aṣọ òkè lásìkò yí
- Ikú ọkọ mi ṣì n dàbí àlá l'ójú mi àtawọn ọmọ