Mọ iye ọdún tó ṣeéṣe kí o lò láyé

Published

Njẹ́ o mọ̀ pé iye ọdún tó ṣeéṣe kí gbogbo ènìyàn yóò lò láyé ti fi ọdún méje pọ̀ si láti 1990?

Irinṣẹ́ òǹkà yìí yóò ràn ọ́ lọ́wọ́ láti ṣe ìṣìrò tìrẹ̀ ní ìbámu pẹ̀lú orílẹ̀èdè tí o ti wá.

Ọdun mejilelaadọrin nireti wa pe o jẹ ọdun to kere ju ti ẹda yoo lo laye - aadọrin ọdun fun ọkunrin, marundinlọgọrin fun obinrin. Ṣugbọn, eyi n yipada pẹlu ọjọ ori. Fun apẹẹrẹ,ireti wa pe ẹni ti o ti pe ọdun mọkandinlaadọrin yoo lo ọdun mẹtadinlogun si.

Fo Móríwú kọjá kí o tẹ̀síwájú

Móríwú

  • Ayo Olaiya joko lori aga, o de igo, wọ ilẹkẹ sọwọ ati ọrun, o rẹrin-in si ẹrọ ayaworan
  • Eniola Oladapo, Àṣoju ajọ INEC
  • Kayode Oduoye lasiko to n ba BBC sọrọ wọ asọ toke tilẹ alawọ dudu, ko si de fila kankan
  • Mo fẹ́ ìyàwó mẹ́rin, a sì jọ lo arísìkí ara wa- Baba Aremu Alapata
  • Oriyomi Hamzat lasiko to n ba BBC sọrọ
  • Olori Tobi Ogunwusi wọ asọ ati gele funfun ti wọn fi owu alawọ ọsan se isẹ si iwaju asọ naa, o si fi ilẹkẹ nla meji sọrun
  • Egungun kan to wọ ẹ̀kú dudu, lo mu awọn igi kekeke to kun fun ina lara lọwọ
  • Awọn afurasi ajọmọgbe kọ ẹyin si ẹrọ ayaworan
  • Imaamu agba fun ilu Ilaro, Alhaji Tajudeen Adewumi
  • Opeyemi Sanyaolu wọ kaba ankara alawọ omi ọsan, o we gele ankara naa, o fi iborun kọrun, o gbe oju soke, o si n lọ ika rẹ
  • Charles Okocha wo aso pupa, o gbe bẹliiti ija to ja dani

Ìròyìn tí àwọn ènìyàn fẹ́ràn jùlọ