Àmì ohùn ṣe pàtàkì nínú èdè Yorùbá púpọ̀

Published

Ayé kò kúkú lọ bí ọ̀pá ìbọn ni ọ̀rọ̀ ayé jẹ́.

Ede olóhùn ni èdè Yorùbá jẹ.

Ọrọ kan ṣoṣo le tumọ si itumọ mẹfa tabi ju bẹẹ lọ pẹlu iyatọ to ba wa lori ami ohùn rẹ.

Ki èdè Yoruba ma le parun ni BBC Yoruba ṣe jade lọ ni kawọn eniyan lọkunrin lobinri fi ami si gbolohun yii.

Oya, ẹyin naa ẹ gbiyanju ẹ wo, ẹ fi ami si gbolohun yii ki a gbọ idahun yin o.