Amputee: Toheeb Abiodun Olaniyan: Ẹ̀rọ lílọ̀ ní ẹni ọdún mẹ́sàn án ni apa kan mi lọ sí

Published

Aforiti ati suuru lo ran mi lọwọ nigba ti ko si owo lati lọ sile ẹkọ mọ- Foga Toheeb

Toheeb Abiodun Olaniyan ni ọdọmọde to kọ lati ṣagbe lainaani pe ọwọ kan oun ti kan.

O ṣalaye fun BBC bo ṣe di ọlọwọ kan lataari aṣo ẹsiki to wọ lasiko to n lọ lọ ẹrọ ata.

O ni oun lọ ṣe isinmi lọdọ Baba oun ni ẹrọ ata ba gbe aṣọ ẹsiki ti oun wọ ni apa kan ba lọ sii.

Bakan naa ni Toheeb tun ṣalaye fun BBC die lara nkan ti oju rẹ ri laye ko to gba kadara.

O menuba igbiyanju rẹ lati kawe ati pe ko si iranlọwọ.