Flying car: Ọkọ̀ tí ń fò, ọ̀nà àbáyọ kan rèé sí ìṣòro 'go slow' lágbègbè rẹ

Published

Imọ ẹrọ ti n goke sii, lara rẹ si ni ọkọ to n fo bi ẹyẹ yii ti wọn ṣẹṣẹ ṣe idanwo rẹ ni ilu Slovakia.

Irufẹ imọ ẹrọ bayii yoo jẹ itura pupọ fun awọn eeyan agbegbe ti sunkẹrẹ fa kẹrẹ ọkọ ti pọ bi ilu Eko lati dẹkun ohun ti awọn eeyan mọ si 'go slow' lọpọlọpọ igba.