You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Ondo 2020: Alága PDP láwọn ò fún ẹgbẹ́ mọ́kànlá tó darapọ̀ mọ́ wọn lówó kankan, ó wù wọ́n ni
Published
Alaga ẹgbẹ oṣelu PDP, Fatai Adams ti sọ pe PDP ko fawọn ẹgbẹ oṣelu mọkanla to darapọ mọ ẹgbẹ naa fun ibo gomina Ondo ọjọ Abamẹta.
O ni awọn oludije gomina ẹgbẹ mọkanla yii ti gba lati sẹ atilẹyin fun oludije fun ipo gomina PDP, Eyitayo Jegede fun ibo to n bọ.
Ọgbẹni Adams ṣalaye pe awọn ẹgbẹ naa sọ pe eto ti PDP ni fawọn eeyan ipinlẹ tẹ wọn lọrun.
Awọn ẹgbẹ oṣelu naa ni AP, SDP, ADC, APP, APGA, APM, NNPP, NRM, LP, YPP ati AAC.
- 'N500 dé fún gbogbo ọmọ tuntun lóṣooṣù bí mo bá di gómìnà Ondo - Adeleye AAC
- Ẹ gbọ́ òhun tí àwọn olùdíjé sípò gómìnà nípínlẹ̀ Ondo sọ nípa Bàbá ìsàlẹ̀...
- Ta ló da 'ewé' bo N4.3bílíọ́nù owó ìjọba Ondo fọ́dún mẹ́wàá?
- Ẹ̀wọ̀n ni wàá gbẹ̀yìn sí, kò sí bóo ṣe dọ́gbọ́n tó - Seyi Makinde wa ègúná ọ̀rọ̀ lé Fayose
- Kìí ṣe emí ni mó ràn amúgbálẹ́gbẹ̀ẹ́ mi tó sọ̀rọ̀ abùkù sí FIBAN níṣẹ́- Wasiu Ayinde