You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Funmi Adewara: Tele Medicine' ní a fi ń ṣàyẹ̀wò èèyàn ìdá ọgọtá láti dènà ìtànkálẹ̀ Covid 19
Inu ile la ti n tọju àwọn to ni Covid 19 ti itọju wọn ko lagbara ju- Dokita Adewara
Patient Appointment Screen, Tele Medicine, Mobile Health àti àwọn ipede tuntun mii ni arun Coronavirus to n ba gbogbo agbye finra yii ti bi lasiko yii.
Gbogbo ile iṣẹ ni agbaye ni ayipada ti de ba ọna ti koowa n gab ṣiṣẹ oojọ won ni eyi ti awọn kan n daṣa 'New Normal'fun un.
Bayii eto iwosan lati lọ ri dokita naa ti yipada bayii, Dokita Funmi Adeara to jẹ oniṣegun oyinbo lasiko Covid 19 ba BBC sọrọ lori awọn irufẹ ayipada wọnyii.
- Ènìyàn 653 míràn tún kún iye àwọn tó ní COVID-19 ní Nàìjíríà
- Ọlọ́paàá ní wọ́n ṣèèṣì yìnbọn pa ọmọ mi tó ń tọ́ ọmọ oṣù mẹ́rin lọ́wọ́ ni- Ìyá Kager
- Ẹ̀bi ta ni pé àwọn ọ̀dọ́bìnrin Nàìjíríà ń há sí Oman?
- Wo àwọn òṣìṣẹ́ kólẹ̀-kódọ̀tí tó ń fi ẹ̀mí wọn wéwu kí Abuja leè mọ́ tónítóní
- Mo ti bẹ̀rẹ̀ sí ń bá àwọn tí a jọ díje nínú ìdìbó abẹ́lé sọ̀rọ̀ kí àláàfíà léè jọba - Akeredolu
Bayii, o ti ṣeeṣe fun ọ lati ba dokita rẹ sọrọ lori aisan rẹ lai de ile iwosan rara.
O tun ṣeeṣe lati ṣe ayẹwo boya o ti lugbadi coronavirus tabi bẹẹkọ nipasẹ foonu rẹ
Koda, o le tun gba 'sample' ẹnu itọ ara rẹ fun ayẹwo lai de ile iwosan ki o si ri esi gba laarin ọjọ meji pere.
- Èèyàn 562 tuntun ló tún ti lùgbàdì COVID-19 ní Nàìjíríà ní àná
- Mo ti bẹ̀rẹ̀ sí ń bá àwọn tí a jọ díje nínú ìdìbó abẹ́lé sọ̀rọ̀ kí àláàfíà léè jọba - Akeredolu
- Kanye West ti bẹ̀rẹ̀ ìpolongo àti díje dupò aàrẹ ilẹ̀ Amẹrika
- Wo àwọn nkan tó yẹ́ kí o mọ̀ nípa 'Awawa Boys', ọ̀kan lára ẹgbẹ́ òkùnkùn tó n dá Eko rú