You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Coronavirus lockdown: Ìyàtọ̀ láàrín ìgbélé ní Nàìjíríà àti ilẹ̀ òkèèrè
Published
Laipẹ yii ni orilẹede Naijiria kede didẹ okun eto konile o gbele lawọn agbegbe kan wa silẹ.
Ọpọ lo ti n kọminu lori ohun to lee ti ẹyin ọrọ naa jade
Arabinrin Sandra to n gbe ni orilẹede Amẹrika ba BBC sọrọ lori bi nnkan ṣe n lọ labẹ eto igbele nibẹ ati iyats to wa ni bo ṣe ri nibẹ ati bo ṣe ri ni Naijiria.
- Àjọ NCDC kéde ènìyàn 381 míràn tó ní ààrùn Covid-19 l'órílẹ̀-èdè Nàìjíríà
- Olateru-Olagbegi II: àkàndá ẹ̀dá tó jọba ní ẹ̀ẹ̀méjì láàrín ọdún márùndínlọ́gbọ̀n síra wọn.
- Owó Abacha sì kú, kò tíì tán, $319m kan sì wà ní UK àti France - Amẹ́ríkà
- Èmi àti Sanyeri ti tọrọ oúnjẹ jẹ rí nílé oninawo torí ebi, ká tó di gbajumọ oṣere