You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Ológbò gan mọ́ yìnyín, ẹ wo bí aláànú yíì ṣe fi ǹkan gbígbóná yọ wọ́n
Published
O fẹ le diẹ, o sì fẹ nira diẹ fun awọn ologbo naa tori bi o ṣe da Coffee gbigbona si wọn lara to si n fa ẹsẹ ati iru wọn yọn ninu yinyin ọhun ni wọn n kerora.
Ẹ wo bi ọkunrin alaanu ara Samaria yii ṣe ran wọn lọwọ ninu ipo ti wọn wa ninu fidio yii.