You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
EkitiRapeCastration: ìgbésẹ̀ míì lè dẹ́kun ìwà ìfipábánilòpọ̀
Titẹ lọdaa ko sọpe ẹni naa ko ṣi ni le ba obinrin sun -Onimọ.
Ọpọlọpọ nkan ni awọn eniyan ti n sọ nipa abadofin ti ijọba ipinlẹ Ekiti n jiroro lori lasiko yii.
Wọn fẹ maa tẹ awọn to ba ṣe ifipabanilopọ lọdaa 'Títẹ àwọn afipábánilopọ̀ lọ́dàá kọ́ ni ọ̀nà àbáyọ sí ìwà ìfipábánilopọ̀'
Dokita Dare Adelusi ti oun funra rẹ jẹ ọmọ Ekiti ni ọgbọn miran bii ka gboriyin fun ẹni to ba huwa ọmọluwabi yoo yi ero ọkan oniṣẹ ibi miran pada.
Bakan naa ni ọmọwe yii gbagbọ pe o yẹ ki ijiya to tọ wa fun gbogbo awọn to ba n huwa ipa lawujọ ni eyi ti yoo kọ awọn to ku lọgbọn ni kete ti agba kan ba ti jin si koto.
- Òjò àrọ̀rọ̀ọ̀dá òní ṣọṣẹ́ tó pọ̀ ni Lekki nipinlẹ Eko
- Ìdí rèé tí mo fi ṣẹ̀ṣẹ̀ sọ̀rọ̀ lẹ́yìn tí wọ́n fipá bámi lopọ̀ lọ́mọ ọdún méje lọ́gọ́ta ọdún sẹ́yìn-Eli
- Ìgbẹ̀yìn ọkùnrin tó pa obìnrin 93 ni America
- Abiy Ahmed gba àmì ẹ̀yẹ̀ ti àláfíà lágbàáyé gẹ́gẹ́ bí ọmọ Africa
- Èrò yapa ní mọ́ṣáláṣí Jimọ̀h láti wá fójú lóúnjẹ lórí ìgbéyàwó òfegè Buhari.
Dare Adelusi gbe ori yin fun ijọba Ekiti pe wọn fẹ dẹkun iwa buruku yii ṣugbọn o gba pe awọn ọna miran wa nitori titẹ lọdaa le ma gbọ iṣoro yii tan.