You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Lai Mohammed: Ẹ ma f'ilara da ogun silẹ
Published
BBC Yoruba ni ifọrọwanilẹnuwo pelu agbenuso ijọba apapọ, Lai Mohammed lori awọn akẹkọbinrin ti wọn jigbe ni Dapchi ati awọn ohun miran to n sẹlẹ ni Naijiria.