Ondo school bus hijack: Mí kò dá àwọn agbébọn náà mọ̀ ṣùgbọ́n wọn kò bojú- Omolayo Ojo

Published

Wọn gbe ibọn sori mi pe ki n tẹle wọn ni- Omolayo Ojo to jẹ oluranlọwọ akékọọ ninu bọọsi.

Adari ile ẹkọ Chimola Schools ni wọn ti da gbogbo ọmọ pada ati pe ko si ẹni to sọnu mọ nile iwe naa.

Omolayo ti wọn gbebọn si lori naa ba BBC sọrọ lori bi gbogbo ẹ ṣe ṣẹlẹ.

Bakan na ni kọmiṣọnna Bolaji Salami to n tukọ agbofinro ipinlẹ Ondo naa ba BBC Yoruba sọrọ lori ibi ti igbesẹ wiwa bọọsi ati awọn oniṣẹ ibi naa ri de duro.